Ezekiel 40:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó tún wọn ìloro, ó jẹ́ ogún igbọnwọ (mita 9). Gbọ̀ngàn kan yí ìloro ẹnu ọ̀nà ká
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si ṣe atẹrigba ọlọgọta igbọnwọ, ani titi de atẹrigba àgbalá yi ẹnu-ọ̀na na ka.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó wọ̀n ọ́n lọ sí àwọn ojú àwọn ìgbéró ògiri gbogbo rẹ̀ yí inú òjú ọ̀nà ó jẹ́ ọgọ́ta ìgbọ̀nwọ́. Ìwọ̀n náà tó àtẹ̀wọ́ ẹnu ọ̀nà tí ó dojúkọ àgbàlá.