Ezekiel 40:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
láti iwájú ẹnu ọ̀nà ní àbáwọlé, títí kan ìloro ẹnu ọ̀nà tí ó wà ninu, jẹ́ aadọta igbọnwọ (mita 25).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati iwaju ẹnu-ọ̀na àtẹwọ titi fi de iwaju iloro ẹnu-ọ̀na ti inu, adọta igbọnwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìjìnà ẹnu ọ̀nà àbáwọlé títí dé ìparí yàrá kéékèèkéé náà àti àwọn ìgbéró ògiri nínú ẹnu ọ̀nà ní a gbé dá jẹ́ àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́.