Ezekiel 40:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Pèpéle kan wà níbi ẹnu ọ̀nà, tí gígùn rẹ̀ rí bákan náà pẹlu ẹnu ọ̀nà, èyí ni pèpéle tí ó wà ní ìsàlẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati okuta itẹlẹ ti iha ẹnu-ọ̀na na ti o kọju si gigun ẹnu-ọ̀na, ani okuta itẹlẹ isalẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
O ṣe ààlà sí ẹ̀gbẹ́ àwọn ẹnu ọ̀nà, ìbú rẹ̀ sì jẹ́ bákan náà pẹ̀lú gígun rẹ̀: èyí jẹ́ pèpéle tí ìsàlẹ̀.