Ezekiel 40:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó wọn ibẹ̀ láti inú ẹnu ọ̀nà kúkúrú títí dé iwájú ìta gbọ̀ngàn inú, ó jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ, (mita 45), ní ìhà ìlà oòrùn ati ìhà àríwá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wọ̀n ibú rẹ̀ lati iwaju ẹnu-ọ̀na isalẹ titi fi de iwaju àgbala inu ti ode, ọgọrun igbọnwọ niha ila-õrun ati niha ariwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà, o wọn jíjìnna rẹ̀ láti inú ìsàlẹ̀ ẹnu ọ̀nà títí dé àgbàlá tí inú; ó jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́ ni ìhà ìlà òòrùn àti tí àríwá.