Ezekiel 40:27 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹnu ọ̀nà kan wà ní ìhà gúsù gbọ̀ngàn inú. Ó wọn ibẹ̀, láti ẹnu ọ̀nà náà sí ẹnu ọ̀nà tí ó wà ní ìhà gúsù, jẹ́ ọgọrun-un (100) igbọnwọ (mita 45).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ẹnu-ọ̀na agbalá ti inu mbẹ li ọ̀na gusu; o si wọ̀n lati ẹnu-ọ̀na de ẹnu-ọ̀na li ọ̀na gusu, ọgọrun igbọnwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àgbàlá ti inú náà ní ẹnu ọ̀nà yìí sí ẹnu ọ̀nà ìta ni ìhà gúsù; Ó jẹ́ ọgọ́rùn-ún ìgbọ̀nwọ́.