Ezekiel 40:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ó mú mi lọ sí ìhà ìlà oòrùn gbọ̀ngàn inú, ó sì wọn ẹnu ọ̀nà rẹ̀, bákan náà ni ó rí pẹlu àwọn yòókù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si mu mi wá si agbalá ti inu nihà ọ̀na ila-õrun: o si wọ̀n ẹnu-ọ̀na na, gẹgẹ bi iwọn wọnyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà, ó mú mi lọ sí àgbàlá tí inú ni ìhà ilà òòrùn, ó sì wọn ẹnu ọ̀nà; ó ní ìwọ̀n kan náà pẹ̀lú àwọn tí ó kù.