Ezekiel 40:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà ó wọn ìloro ẹnu ọ̀nà tí ó wà ninu, ó jẹ́ igbọnwọ mẹjọ (mita 4),
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wọ̀n iloro ẹnu-ọ̀na ti inu, ije kan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà, ó wọn àtẹ̀wọ́ ẹnu ọ̀nà: