Ezekiel 41:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ati àwọn yàrá ẹ̀gbẹ́ gbọ̀ngàn fẹ̀ ní ogún igbọnwọ (mita 10), yíká gbogbo ẹ̀gbẹ́ tẹmpili.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati lãrin yará na, ogún igbọnwọ ni gbigborò, yi ile na ka ni ihà gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Yàrá àwọn àlùfáà jẹ́ ogun ìgbọ̀nwọ́ ni fífẹ̀ yí pó témpílì náà.