Ezekiel 44:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Wọn kò ní ní ilẹ̀ ìní nítorí èmi ni ìní wọn, ẹ kò ní pín ilẹ̀ fún wọn ní Israẹli, èmi ni ìpín wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ogún ni yio jẹ fun wọn: emi ni ogún wọn: ẹ kì yio si fun wọn ni ini ni Israeli: emi ni ini wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“ ‘Èmi ni kì ó jẹ́ ogún tí àwọn Àlùfáà yóò ní. Ẹ kò gbọdọ̀ fún wọn ni ìpín kankan ní Ísírẹ́lì; Èmi ni yóò jẹ́ ìpín wọn.