Ezekiel 44:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn alufaa kò gbọdọ̀ jẹ ohunkohun tí ó bá kú fúnrarẹ̀ tabi tí ẹranko burúkú bá pa, kì báà jẹ́ ẹyẹ tabi ẹranko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo okú nkan, ati ohun ti a fà ya ninu ẹiyẹ tabi ninu ẹranko, ni awọn alufa kì yio jẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn àlùfáà kò gbọdọ̀ jẹ́ ohunkóhun bí i ẹyẹ tàbí ẹrankọ, tí ó ti kú fúnra rẹ̀ tàbí èyí ti ẹranko ńlá fà ya.