Ezekiel 45:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Àwọn ọmọ Israẹli gbọdọ̀ kó àwọn nǹkan ìrúbọ náà fún àwọn ọba Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo enia ilẹ na ni yio mu ẹbọ yi wá fun olori ni Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ènìyàn ni ilẹ̀ náà ni yóò kópa nínú ẹ̀bùn pàtàkì fún ìlò àwọn ọmọ aládé ni Ísírẹ́lì.