Ezekiel 45:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ní ọjọ́ náà ọba yóo pa ọ̀dọ́ akọ mààlúù kan fún ẹbọ ìmúkúrò ẹ̀ṣẹ̀ fún ara rẹ̀ ati fún gbogbo àwọn ará ìlú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati li ọjọ na ni ọmọ-alade yio pèse ẹgbọ̀rọ akọ malu fun ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ fun ara rẹ̀ ati fun gbogbo enia ilẹ na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ náà ní ọmọ aládé yóò pèsè akọ màlúù gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ẹbọ ẹ̀sẹ̀ fún ara rẹ̀ àti fún gbogbo ènìyàn ni ilẹ̀ náà.