Ezekiel 46:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọba yóo bá wọn wọlé nígbà tí wọ́n bá wọlé, nígbà tí wọ́n bá sì jáde, yóo bá wọn jáde.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati olori ti o wà lãrin wọn, nigbati nwọn ba wọle, yio wọle; nigbati nwọn ba si jade, yio jade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọmọ aládé gbọdọ̀ wà ní àárin wọn, kí ó wọlé nígbà tí wọn bá wọlé, kí ó sì jáde nígbà tí wọn bá jáde.