Ezekiel 46:22 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní igun mẹrẹẹrin ni àwọn gbọ̀ngàn kéékèèké yìí wà. Ó gùn ní ogoji igbọnwọ (mita 20), ó sì fẹ̀ ní ọgbọ̀n igbọnwọ (mita 15) àwọn mẹrẹẹrin sì rí bákan náà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ni igun mẹrẹrin agbalá na, ni agbalá ti a kànpọ ologoji igbọnwọ ni gigùn, ati ọgbọ̀n ni ibú: awọn igun mẹrẹrin wọnyi jẹ iwọ̀n kanna.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìgun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ìta àgbàlá tí ó pẹnupọ̀, ogójì ìgbọ̀nwọ́ ni gígùn àti ọgbọ̀n ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ̀; àgbàlá kọ̀ọ̀kan ni igun kọ̀ọ̀kan jẹ́ ìwọ̀n kan náà.