Ezekiel 46:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Wọ́n fi òkúta kọ́ igun mẹrẹẹrin, ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn yípo. Wọ́n sì kọ́ ibi ìdáná wọn mọ́ ara ògiri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọwọ́ ile kan si wà yika ninu wọn, yika awọn mẹrẹrin, a si ṣe ibudaná si abẹ ọwọ́ na yika.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní agbègbè inú ikọ̀ọ̀kan nínú àgbàlá náà ni ọwọ́ ilẹ̀ kan wà yíká wọn, a sì ṣe ibi ìdáná si abẹ́ ọwọ́ náà yípo.