Ezekiel 46:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni ó wí fún mi pé, “Àwọn ilé ìdáná níbi tí àwọn alufaa tí óo wà níbi pẹpẹ yóo ti máa se ẹran ẹbọ àwọn eniyan mi nìyí.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si wi fun mi pe, Wọnyi ni ibi awọn ti nsè, nibiti awọn iranṣẹ ile na yio ma se ẹbọ awọn enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì wí fún mi pé, “Ìwọ̀nyí ni àwọn ilé ìdáná níbi tí o ń ṣiṣẹ́ ìránṣẹ́ nínú tẹ́ḿpìlì yóò ti ṣe ẹbọ fún àwọn ènìyàn.”