Ezekiel 46:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọ̀dọ́ aguntan mẹfa tí kò lábàwọ́n ati àgbò kan tí kò lábàwọ́n ni ọba yóo fi rú ẹbọ ọrẹ sísun sí OLUWA ní ọjọ́ ìsinmi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọrẹ-ẹbọ sisun ti olori na yio rú si Oluwa ni ọjọ isimi, yio jẹ ọdọ-agutan mẹfa alailabawọn, ati agbò kan alailabàwọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọrẹ ẹbọ sísun tí ọmọ aládé mú wá fún OLÚWA ni ọjọ́ ìsinmí ní láti jẹ́ ọ̀dọ́ àgbò mẹ́fà àti àgbò kan, gbogbo rẹ̀ gbọdọ̀ jẹ́ aláìlábùkù.