Ezekiel 46:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹnu ọ̀nà àbáwọlé náà ni ọba yóo gbà wọlé, ibẹ̀ náà ni yóo sì gbà jáde.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati olori na yio ba si wọle, ọ̀na iloro ẹnu-ọ̀na ni yio ba wọle, yio si ba ọ̀na rẹ̀ jade.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ọmọ aládé bá wọlé, ó gbọdọ̀ gbá àtẹ̀wọ̀ ẹnu ọ̀nà wọ inú, kí ó sì gba ibẹ̀ jáde.