Ezekiel 47:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Bí ààlà ilẹ̀ náà yóo ti lọ nìyí: ní apá àríwá, ilẹ̀ náà yóo bẹ̀rẹ̀ láti Òkun Ńlá, yóo gba Etiloni títí dé ẹnubodè Hamati, títí dé ẹnu ibodè Sedadi,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Eyi ni yio si jẹ ãlà ilẹ na nihà ariwa, lati okun nla, ni ọ̀na Hetloni, bi a ti nlọ si Sedadi;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èyí yìí ni yóò jẹ́ ààlà ilẹ̀ náà: “Ní ìhà àríwá yóò lọ láti omi òkun ńlá ní ibi ọ̀nà Hétílónì gbà tí Hámátì sí Sídádì,