Ezekiel 47:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ní ìhà gúsù, ilẹ̀ yín yóo lọ láti Tamari dé àwọn odò Meriba Kadeṣi, títí yóo fi kan odò Ijipti títí lọ dé Òkun-ńlá. Èyí ni yóo jẹ́ ààlà ilẹ̀ náà ní apá ìhà gúsù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ihà gusu si gusu, lati Tamari titi de omi ijà ni Kadeṣi, pẹ̀tẹlẹ si okun nla. Eyi ni ihà gusu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ní ìhà gúsù yóò lọ láti Támérì títí dé ibi omi méríba Kádési, lẹ́yìn náà ni ìhà wádìí tí Éjíbítì lọ sí òkun ńlá. Èyí ni yóò jẹ́ ààlà gúsù.