Ezekiel 47:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ààrin ẹ̀yà tí àjèjì náà bá ń gbé ni kí ẹ ti pín ilẹ̀ ìní tirẹ̀ fún un. Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si ṣe pe, ni ẹ̀ya ti alejò ba ṣe atipo, nibẹ̀ li ẹ o fun u ni ogún, ni Oluwa Ọlọrun wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní àárin ẹ̀yàkẹyà tí àwọn àlejò ń gbé; wọn gbọdọ̀ fi ìní tirẹ̀ fún-ún,” ní OLÚWA Ọba pa lásẹ.