Ezekiel 48:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn òṣìṣẹ́ ààrin ìlú tí wọ́n bá wá láti inú àwọn ẹ̀yà Israẹli ni yóo máa dá oko níbẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti mba nsìn ilu-nla na yio si ma sìn i, lati inu gbogbo ẹ̀ya Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn òsìsẹ́ láti ìlú ńlá náà, tí ó ń dáko níbẹ̀ yóò wá láti gbogbo àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì.