Ezekiel 48:28 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́gbẹ̀ẹ́ agbègbè Gadi ní ìhà gúsù, ààlà ilẹ̀ náà yóo lọ láti Tamari títí dé ibi àwọn odò Meriba Kadeṣi, títí dé àwọn odò Ijipti, tí ó fi lọ dé Òkun Ńlá.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ni àgbegbe Gadi, ni ihà gusu si gusu, àgbegbe na yio jẹ lati Tamari de omi ijà ni Kadeṣi, ati si odò, titi de okun nla.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ààlà tí gúsù Gádì yóò dé gúsù láti Támárì lọ sí odò Méríbà Kádésì lẹ́yìn náà títí dé Wádì ti Éjíbítì lọ sí òkun ńlá fún àwọn ẹ̀yà Ísírẹ́lì, ìwọ̀nyí ní yóò sì jẹ́ ìpín wọn” ní OLÚWA Ọba wí.