Ezekiel 5:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA ní: “Ìwọ ọmọ eniyan, mú idà kan tí ó bá mú, lò ó gẹ́gẹ́ bí abẹ ìfárí, kí o fi fá orí ati irùngbọ̀n rẹ. Mú òṣùnwọ̀n tí a fi ń wọn nǹkan kí o fi pín irun tí o bá fá sí ọ̀nà mẹta.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
IWỌ, ọmọ enia, mu ọbẹ mimú, mu abẹ onigbajamọ̀, ki o si mu u kọja li ori rẹ, ati ni irùngbọn rẹ: si mu oṣuwọ̀n lati wọ̀n, ki o si pin irun na.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Báyìí, ọmọ ènìyàn, mú ìdá tí ó mú kí o sì fi se abẹ ìfárí onígbàjámọ̀, kí o fi fá irun orí àti irùngbọ̀n rẹ. Fi irun yìí sórí ìwọ̀n kí o sì pín in.