Ezekiel 5:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo rán ìyàn ati àwọn ẹranko burúkú si yín, wọn óo sì pa yín lọ́mọ. Àjàkálẹ̀ àrùn ati ikú yóo bẹ́ sílẹ̀ láàrin yín, n óo sì jẹ́ kí ogun pa yín. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ni emi o rán iyàn ati ẹranko buburu si nyin, nwọn o si gbà ọ li ọmọ, ajàkalẹ arùn ati ẹjẹ̀ yio si kọja lãrin rẹ, emi o si mu idà wá sori rẹ. Emi Oluwa li o ti sọ ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò rán ìyàn àti ẹranko búburú sí i yín, wọn yóò fi yín sílẹ ni àìlọ́mọ. Àjàkálẹ̀ àrùn àti ìtàjẹ̀-sílẹ̀ yóò kọjá láàrin yín. Èmi yóò si mú idà wá sórí rẹ. Èmi OLÚWA ló sọ bẹ́ẹ̀.”