Ezekiel 5:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mú díẹ̀ ninu irun náà kí o dì í sí etí ẹ̀wù rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ o si mu iye diẹ nibẹ, iwọ o si dì wọn si eti aṣọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n mú díẹ̀ nínú irun yìí kí o sì ta á mọ́ etí aṣọ rẹ.