Ezekiel 5:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mú díẹ̀ ninu èyí tí o dì sí etí ẹ̀wù, jù ú sinu iná kí ó jóná; iná yóo sì ti ibẹ̀ ṣẹ́ sí gbogbo ilé Israẹli.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Si tun mu ninu wọn, ki o si sọ wọn si ãrin iná, ki o si sun wọn ninu iná; lati inu rẹ̀ wá ni iná o ti jade wá si gbogbo ile Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tún ju díẹ̀ nínú irun yìí sínú iná, kí o sun ún níná. Torí pé láti ibẹ̀ ni iná yóò ti jáde lọ sí gbogbo ilé Ísírẹ́lì.