Ezekiel 6:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọwọ́ mi óo tẹ̀ wọ́n; n óo sọ ilẹ̀ wọn di ahoro ati òkítì àlàpà, ní gbogbo ibùgbé wọn, láti ibi aṣálẹ̀ títí dé Ribila. Wọn óo wá mọ̀ nígbà náà pé èmi ni OLUWA.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bẹ̃ li emi o nà ọwọ́ mi jade sori wọn, emi o si sọ ilẹ na di ahoro, nitotọ, yio di ahoro jù aginju iha Diblati lọ, ninu gbogbo ibugbe wọn: nwọn o si mọ̀ pe emi li Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò na ọwọ́ mi jáde sí wọn láti mú kí ilẹ̀ náà ṣòfò kí ó sì dahoro dé aṣálẹ̀ ìhà Díbílà-ní gbogbo ibùgbé wọn. Nígbà náà ni wọn ó mọ̀ pé Èmi ni OLÚWA.’ ”