Ezekiel 8:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó sì bi mí pé, “Ìwọ ọmọ eniyan, ǹjẹ́ o rí ohun tí wọn ń ṣe yìí? O óo tún rí nǹkan ìríra tí ó ju èyí lọ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li o sọ fun mi pe, Iwọ ri eyi, Iwọ ọmọ enia? tun yipada, iwọ o si ri ohun irira ti o tobi ju wọnyi lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sọ fún mi pé, “Ṣé o rí báyìí, ọmọ ènìyàn? Ìwọ yóò tún rí ìríra tó ga jù èyí lọ.”