Ezekiel 8:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, n óo bínú sí wọn, n kò ní fojú fo iṣẹ́ wọn, n kò sì ní ṣàánú wọn. Wọ́n ìbáà máa kígbe sí mi létí, n kò ní dá wọn lóhùn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi pẹlu yio si fi irúnu ba wọn lò: oju mi kì yio dasi, bẹ̃li emi kì yio ṣãnu: ati bi o tilẹ ṣepe nwọn fi ohùn rara kigbe li eti mi, sibẹ emi kì yio gbọ́ ti wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, ń o fi ìbínú bá wọn wí; n kò ní i dá wọn sí bẹ́ẹ̀ ni n kò sì ní fojú àánú wò wọ́n. Bí wọ́n tilẹ̀ ń pariwo sí mi létí, n kò ní fetí sí wọn.”