Ezekiel 9:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ògo Ọlọrun Israẹli ti gbéra kúrò lórí àwọn Kerubu tí ó wà, ó dúró sí àbáwọlé. Ó ké sí ọkunrin tí ó wọ aṣọ funfun náà, tí ó sì ní àpótí ìkọ̀wé kan lẹ́gbẹ̀ẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ogo Ọlọrun Israeli si ti goke kuro lori kerubu, eyi ti o ti wà, si iloro ile. O si pe ọkunrin na ti o wọ aṣọ ọgbọ̀, ti o ni ìwo-tàdawa akọwe li ẹgbẹ́ rẹ̀:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ògo Ọlọ́run sì gòkè kúrò lórí Kérúbù, níbi tó wà tẹ́lẹ̀ lọ síbi ìloro tẹ́ḿpìlì. Nígbà náà ni OLÚWA pe ọkùnrin tó wọ aṣọ funfun lẹlẹ tí ó sì ní ohun ìkọ̀wé lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀.