Ezra 1:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Iye àwọn nǹkan náà nìyí: Ẹgbẹrun kan (1,000) àwo wúrà, ẹgbẹrun kan (1,000) àwo fadaka, àwo turari mọkandinlọgbọn;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iye wọn si li eyi: ọgbọn awo-pọ̀kọ wura, ẹgbẹrun awo-pọ̀kọ fadaka, ọbẹ mọkandilọgbọn,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni iye wọn: Ọgbọ̀n àwo wúrà — (30) ẹgbẹ̀rún àwo fàdákà — (1000) Àwo ìrúbọ fàdákà mọ́ kàndínlọ́gbọ̀n — (29)