Ezra 10:23 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Orúkọ àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n fẹ́ àwọn obinrin àjèjì nìwọ̀nyí: Josabadi, Ṣimei, Kelaya, (tí àdàpè rẹ̀ ń jẹ́ Kelita), Petahaya, Juda, ati Elieseri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ Lefi; Josabadi, ati Ṣimei, ati Kelaiah (eyi ni Kelita) Petahiah, Juda, ati Elieseri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lára àwọn ọmọ Léfì: Jósábádì, Ṣíhíméì, Kéláéáyà (èyí tí í se Kélítà), Pétíáíyà, Júdà àti Élíásérì.