Ezra 10:24 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ninu àwọn akọrin, Eliaṣibu nìkan ni ó fẹ́ obinrin àjèjì. Orúkọ àwọn aṣọ́nà tí wọ́n fẹ́ obinrin àjèjì nìwọ̀nyí: Ṣalumu, Telemu, ati Uri.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn akọrin pẹlu; Eliaṣibu: ati ninu awọn adèna; Ṣallumu, ati Telemi, ati Uri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àwọn akọrin: Élíásíbù. Nínú àwọn asọ́nà: Sálúmù, Télémù àti Úrì.