Ezra 10:28 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu ìdílé Bebai: Jehohanani, Hananaya, Sabai, ati Atilai.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Bebai pẹlu; Jehohanani, Hananiah, Sabbai ati Atlai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àwọn ìran Bébáì: Jéhóánánì, Hánánáyà, Ṣábábáì àti Átaláì.