Ezra 10:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu ìdílé Bani: Meṣulamu, Maluki, ati Adaaya, Jaṣubu, Ṣeali, ati Jeremotu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ Bani; Meṣullamu, Malluki, ati Adaiah, Jaṣubu, ati Ṣeali ati Ramoti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àwọn ìran Bánì: Mésúlámì, Málúkì, Ádáyà, Jásílíbù, Ṣéálì àti Jérémótì.