Ezra 10:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ninu ìdílé Harimu: Elieseri, Iṣija, ati Malikija; Ṣemaaya, ati Ṣimeoni.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ Harimu; Elieseri, Isṣjah, Malkiah, Ṣemaiah, Ṣimeoni,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àwọn ìran Hárímù: Élíásérì, Ísíjà, Málíkíjà àti Ṣémáíáyà, Ṣíméínì,