Ezra 10:43 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ninu ìdílé Nebo: Jeieli, Matitaya, Sabadi, Sebina, Jadai, Joẹli, ati Benaaya.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ninu awọn ọmọ Nebo; Jeieli, Mattitiah, Sabadi, Ṣebina, Jadau, ati Joeli, Benaiah.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nínú àwọn ìran Nébò: Jérélì, Mátítaíyà, Ṣábádì, Ṣábínà, Jádáì, Jóélì àti Bénáíáyà.