Ezra 2:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Ateri láti inú ìran Hesekaya jẹ́ mejidinlọgọrun-un
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Ateri ti Hesekiah, mejidilọgọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìran Átérì nípaṣẹ̀ Heṣekáyà jẹ́ méjìdínlọ́gọ́rin — (78) —