Ezra 2:36 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Iye àwọn alufaa tí wọ́n pada dé láti, oko ẹrú wọn nìwọ̀nyí: Àwọn ọmọ Jedaaya láti inú ìdílé Jeṣua jẹ́ ẹẹdẹgbẹrun ó lé mẹtalelaadọrin (973)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn alufa; awọn ọmọ Jedaiah, ti idile Jeṣua, ogúndilẹgbẹrun o din meje.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn Àlùfáà: — Àwọn Ìran Jédáíyà (nípaṣẹ̀ ìdílé Jéṣúà) jẹ́ ogúndínlẹ́gbẹ̀rún ó-dín-méje — (973) —