Ezra 2:40 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Iye àwọn ọmọ Lefi tí wọ́n pada dé láti oko ẹrú nìwọ̀nyí: Àwọn ọmọ Jeṣua ati Kadimieli láti inú ìran Hodafaya jẹ́ mẹrinlelaadọrin
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Lefi: awọn ọmọ Jeṣua ati Kadmieli ti awọn ọmọ Hodafiah, mẹrinlelãdọrin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ará Léfì: — Àwọn Ìran Jésúà àti Kádíméì (ti ìdílé Hódáfíà) jẹ́ mẹ́rìnléláàdọ́rin — (74)