Ezra 2:42 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Iye àwọn ọmọ àwọn aṣọ́nà: àwọn ọmọ Ṣalumu ati àwọn ọmọ Ateri, àwọn ọmọ Talimoni ati àwọn ọmọ Akubu; àwọn ọmọ Hatita ati àwọn ọmọ Ṣobai jẹ́ mọkandínlogoje (139)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ awọn adena: awọn ọmọ Ṣalumu, awọn ọmọ Ateri, awọn ọmọ Talmoni, awọn ọmọ Akkubu, awọn ọmọ Hatita, awọn ọmọ Ṣobai, gbogbo wọn jẹ, mọkandilogoje.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn aṣọ́bodè: — Áwọn ara Ṣálúmì, Átérì, Tánímónì, Ákúbù, Hátítà àti Ṣóbíà jẹ́ mọ́kàndínlógóje — (139)