Ezra 2:58 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn òṣìṣẹ́ tẹmpili ati àwọn ọmọ àwọn iranṣẹ Solomoni jẹ́ irinwo ó dín mẹjọ (392).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn Netinimu, ati awọn ọmọ awọn iranṣẹ Solomoni, jẹ irinwo o din mẹjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìrańṣẹ́ tẹ́ḿpìlì àti àwọn ìran àwọn ìranṣẹ́ Ṣólómónì jẹ́ irinwó-ó-dín-mẹ́jọ — (392)