Ezra 2:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Pahati Moabu láti inú ìran Jeṣua ati Joabu jẹ́ ẹgbẹrinla lé mejila (2,812)
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Pahati-Moabu ninu awọn ọmọ Jeṣua, ati Joabu, ẹgbẹrinla o le mejila.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìran Páhátì-Móábù (nípaṣẹ̀ àwọn ọmọ Jéṣúà àti Jóábù) jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì àti ẹgbẹ̀rin-ó-le-méjìlá — (2,812) —