Ezra 2:60 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Delaaya, àwọn ọmọ Tobaya, ati àwọn ọmọ Nekoda. Gbogbo wọn jẹ́ ọtalelẹgbẹta ó dín mẹjọ (652).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọ Delaiah, awọn ọmọ Tobiah, awọn ọmọ Nekoda, ãdọtalelẹgbẹta o le meji.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ìran — Déláyà, Tóbíyà àti Nékódà jẹ́ àádọ́tàlélẹ́gbẹ̀ta-ó-lé-méjì — (652)