Ezra 2:61 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n jẹ́ ọmọ alufaa ninu wọn nìwọ̀nyí: àwọn ọmọ Habaya, àwọn ọmọ Hakosi, ati àwọn ọmọ Basilai (tí ó fẹ́ aya ninu ìdílé Basilai ará Gileadi, tí wọ́n sì ń fi orúkọ àna rẹ̀ pe àwọn ọmọ rẹ̀).
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati ninu awọn ọmọ awọn alufa: awọn ọmọ Habaiah, awọn ọmọ Hakosi, awọn ọmọ Barsillai, ti o fẹ ọkan ninu awọn ọmọ Barsillai obinrin, ara Gileadi li aya, a si pè e nipa orukọ wọn;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Pẹ̀lú láti àárin àwọn àlùfáà: — Àwọn ìránṣẹ — Hóbátà, Hákósì àti Báríṣíláì (ọkùnrin tí ó fẹ́ ọmọbìnrin Báríṣíláì ará Gílíádì a sì ń fi orúkọ náà pè é). —