Ezra 5:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn ní ọdún kinni ìjọba Kirusi, ọba Babiloni, ó fi àṣẹ sí i pé kí wọ́n lọ tún tẹmpili náà kọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn li ọdun ekini Kirusi ọba Babiloni, Kirusi ọba na fi aṣẹ lelẹ lati kọ́ ile Ọlọrun yi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ní ọdún kìn-ín-ní ìjọba Ṣáírúsì ọba Bábílónì, ọba Ṣáírúsì pàṣẹ pé kí a tún ilé Ọlọ́run yìí kọ́.