Ezra 5:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ati pé, kí ni orúkọ àwọn tí wọ́n ń kọ́ ilé yìí?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni awa wi fun wọn bayi, pe, Orukọ awọn ọkunrin ti nkọ́ ile yi ti ijẹ?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n sì tún béèrè pé, “Kí ni orúkọ àwọn ọkùnrin tí ó ń kọ́ ilé yìí?”
Recommended Reading