Ezra 5:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Sí Dariusi ọba, kí ọba ó pẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn fi iwe ranṣẹ si i, ninu eyiti a kọ bayi; Si Dariusi, ọba, alafia gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìròyìn tí wọ́n fi ránṣẹ́ sí i kà báyìí pé: Sí ọba Dáríúsì: Àlàáfíà fún un yín.