Ezra 7:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà, ní àkókò ìjọba Atasasesi, ọba Pasia, ọkunrin kan wà, orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹsira, ọmọ Seraaya, ọmọ Asaraya, ọmọ Hilikaya,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
NJẸ lẹhin nkan wọnyi, ni ijọba Artasasta ọba Persia, Esra ọmọ Seraiah, ọmọ Asariah, ọmọ Hilkiah,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn nǹkan wọ̀nyí, ní àkókò ìjọba ọba Aritaṣéṣéṣì ní Páṣíà, Ẹ́sírà ọmọ Ṣéráíyà, ọmọ Ásáríyà, ọmọ Hílíkíyà,